Jump to content

Federal Secretariat

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Federal Secretariat jẹ ile oní pètésì meedogun kan ni Ikoyi, ìpínlè Eko. [1] [2]

Wọ́n kọ́ ilé náà ní ọdún 1976 fún àwon egbé Nigerian Federal Civil Service. Ile náà dúró láti ma wúlò fún ídí ti wón fi ko ni odun 1991 lẹhin ìgbà ti wón gbé olú-ìlú Nàìjíríà láti ìpínlè Eko lọ si Abuja, FCT.

Lati ọdun 2006, Ijọba ipinlẹ Eko ati ilé-isé olùdásílè kan(Resort International Limited), èni tí o padà jáwé olúborí ninú ejó náà TiVo si rí ilé náà gbà. [3]

Botilẹjẹpe àjo NAFDAC n lo apakan ilé màá, kò si èni ti óún lo òpòlopò apá ilé náà. [4] [5]