Federal University, Gusau
Ìrísí
Federal University Gusau, tí a tún mọ̀ nípasẹ̀ adápé FUGUS, tí ó wá nìGusau Zamfara State, Nigeria jẹ ọkan nínú àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga tí ó kẹhìn tí á pínnú ní ọdún 2010.
Ìmúsẹ tí ìpele àkọkọ tí ìmọràn bẹ̀rẹ ní Kínní, 2011, pẹlú idasilẹ tí Áwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga mẹsan, nígbà tí ìpele Kejì tí ò kàn awọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga mẹta tí o kú pẹlú Federal University Gusau tí dasilẹ ní 2013, ní àkókò Ààrẹ Goodluck Jonathan . pẹ̀lú mẹta faculties, Humanities àti Education, Management àtiSocial Science, àti Imọ .