Federal University of Technology, Minna
Federal University of Technology, Minna jé yunifásitì tí ìjoba ní minna, ìpínlè Niger, ní orílè-èdè Nàìjíríà. A da kalè ni ojo kíni Osù Keji, odun 1983 [1]. Oruko olori alákókó ti yunifásitì na ní J.O Ndagi [2] Oruko olórí(Vice Chancellor) tó wà lori oyè lowo ni Ojogbon Abdullahi Bala [1]

Àwon èka èkó(faculties) Yunifásitì na[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
• Eka èkó Engineering and engineering technology [3]
• Èka èkó agriculture and agricultural technology [4]
• Èka èkó environmental technology
• Èka èkó information and communication technology [5]
• Èka èkó life sciences
• Èka èkó physical science
• Èka èkó science àti technological innovation.
Àwon gbajugbaja omo yunifásitì na télèrí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ 1.0 1.1 "Technology for Empowerment". Federal University of Technology Minna - Technology for Empowerment. 2018-08-13. Retrieved 2022-03-01.
- ↑ "FEDERAL UNIVERSITY OF TECHNOLOGY MINNA (FUTMINNA)". Glimpse Nigeria. 2020-06-24. Archived from the original on 2022-03-01. Retrieved 2022-03-01.
- ↑ "JPAGETITLE". JPAGETITLE. Retrieved 2022-03-01.
- ↑ "Home". School of Agriculture and Agricultural Technology. Retrieved 2022-03-01.
- ↑ "Home". School of Information and Communications Technology. Retrieved 2022-03-01.
- ↑ 6.0 6.1 "10 Best Universities in Nigeria, their Faculties and notable alumni.". educationplanetonline.com. 2021-03-16. Retrieved 2022-03-01.