Fela Sowande

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Fela Sowande je olorin ara Naijiria.

A ma ń pè Sowande ni ó pò lọ pọ ìgbà ni Ọlọ́run tó mú awokose orin ìwọ ọrùn Áfríkà sì nù Orin kílasíkà. Àpèjá orúkọ rẹ̀ ni Olórí Olufela Obafunmilayo Sowande. Abíi ni ọjọ́ ìkankàndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kàrún ọdún 1905 ni Abẹ́òkúta, Nàìjíríà. [1]

Ó má n kọ orin oríṣiríṣi. Lẹ́yìn tó lọ ilé ìwé ìmò-ẹ̀rọ fún ìgbà díè, ó padà sí iṣẹ́ orin. Lẹ́yìn ogun àgbáyé kejì, ó jẹ ipò adarí orin fún iṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́. Ní ọdún 1962, Sowande dá ilé ìwé orin sí ilẹ̀ Nsukka .[2]

Bàbá Sowande, Emmanuel Sowande, jẹ́ mínísítà ìhìn rere àti ara àwọn Aṣáájú-ọ̀nà orin ìjọ àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù ni ilẹ̀ Nàìjíríà. Bàbá rẹ̀ jẹ́ olórin tó kúnjú òṣùwọ̀n. Àti ọwọ́ rè ni Fela ti kọ́ láti tẹ dùùrù àti àwọn àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ nkan miran tí ó jẹ mọ́ Orin ní ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀ [3].


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://www.classicfm.com/discover-music/fela-sowande-nigerian-composer-music-life-career-african-suite/#primary
  2. http://www.dramonline.org/albums/african-heritage-symphonic-series-vol-i/notes
  3. https://citeseerx.ist.psu.edu/viewdoc/summary?doi=10.1.1.693.8730