Jump to content

Femi Osofisan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Femi Osofisan NNOM
Femi Osofisan


Babafemi Adeyemi Osofisan je olukowe ati elere drama ara ile Naijiria. O tun je ojogbon ni eka-eko Litireso ni Yunifasiti ilu Ibadan.