Yunifásítì ìlú Ìbàdàn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Yunifasiti ilu Ibadan)
Jump to navigation Jump to search
Yunifásítì ìlú Ìbàdàn
University of Ibadan
Fáìlì:Logoui.png
Established1948
TypePublic
Vice-ChancellorProfessor Abel Idowu Olayinka
Postgraduatespgschool.ui.edu.ng
LocationIbadan, Oyo, Nigeria

Yunifásítì ìlú Ìbàdàn (UI)

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Itan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Kenneth Dike Library, University of Ibadan

Aseda Ile eko Yunifasiti ti ilu Ibadan ni ojo ketadinlogun, osu kokanla, odun 1948.[1] Rt. Hon. Sir Abubakar Tafawa Balewa je eni akoko lati je ipo Baba Isale fun ynuifasiti yi. O si je oye yi ni ayeye kan, ti a ranti fun Ilu Gangan, ti o si waye lori papa isere Yunifasiti yi, ni odun 1963. Kenneth Dike si ni omo orileede Naijiria akoko ti o ma je ipo Giwa Yunifasiti na. Oruko re lasi fi so Yara Iwe yunifasiti yi.

Isakoso[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Awon Asiwaju yunifasiti ilu Ibadan lowolowo ni:[2]

Eniyan
Ipo Oruko
Alejo Muhammadu Buhari
Baba Isale Sultan of Sokoto, Alhaji Saad Abubakar
Alaga Igbimo Nde Joshua Mutka Waklek
Giwa ile eko Ojogbon Abel Idowu Olayinka
Igbakeji Giwa (Eto Ise Akoso) Ojogbon Kayode Oyebode Adebowale
Igbakeji Giwa (Eto Eko) Ojogbon Adeyinka Abideen Aderinto
igbakeji Giwa (Eto Awari, Iseda ati Ifowosowopo fun Idagbasoke) Ojogbon Olanike Kudirat Adeyemo
Akowe Iya afin Olubunmi Faluyi
Akapo Omowe Michael O. Alatise
Adari fun Yara Iwe Omowe Helen O. Komolafe-Opadeji

Eka[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]