French Village, Badagry
Ìrísí
French Village, Badagry tí àpèjá orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ The Nigerian French Language Village jẹ́ ilé ìwé gíga fún ẹ̀kọ́ èdè Faransé ti Ìjọba Àpapọ̀ tí ó wà ní ìlú Àjárá, ní Ìjọba-ìbílẹ̀ Badagry, ní Ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ilé ìwé gíga ti àwọn Yunifásítì káàkiri orílẹ̀ èdè Nàìjíríà máa ń wá kẹ́kọ̀ọ́ nípa èdè Faransé sí í. [1] [2] [3]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "French Village partners DTCA, signs MOU - Nigeria and World NewsGuardian Arts - The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News. Retrieved 2020-01-10.
- ↑ "The Nigeria French Language Village". The Nigeria French Language Village. Retrieved 2020-01-10.
- ↑ "Nigeria French Language Village, Badagry". Academia.edu (in Èdè Afrikani). 2015-08-03. Retrieved 2020-01-10.