Funmi Iyanda

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Olufunmilola Aduke Iyanda (ojoibi 27 July 1971), to gbajumo lasan bi Funmi Iyanda, je olukede, oniroyin ati alaroko ara Naijiria. O se atokun ati olootu eto iforowero lori NTA to unje New Dawn with Funmi, to bo si ori afefe fun odun mejo.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]