Gùyánà Fránsì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Gùyánà Fránsì
Guyane
—  Overseas region of France  —

Àsìá

Logo
Country France
Prefecture Cayenne
Departments 1
Ìjọba
 - President Antoine Karam (PSG)
Ààlà
 - Iye àpapọ̀ 83,534 km2 (32,252.7 sq mi)
Olùgbé (2008)
 - Iye àpapọ̀ 221,500
 Ìṣúpọ̀ olùgbé 2.7/km2 (6.9/sq mi)
Àkókò ilẹ̀àmùrè UTC-3 (UTC-3)
GDP/ Nominal € 2.3 billion (2006)[1]
GDP per capita € 11,690 (2006)[1]
NUTS Region FR9
Ibiìtakùn www.ctguyane.fr

Gùyánà Fránsì[2] (Faranse: Guyane française, pípè ní Faransé: [ɡɥijan fʁɑ̃sɛz]; Guyaneèdè àjùmọ̀lò) jẹ́ ìpínlẹ̀ kan lára ilẹ̀ Fránsì ní apá àríwá Gúúsù Amẹ́ríkà. Gùyánà Fránsì budo lari Sùrìnámù ní ìwọ oòrùn àti Bràsíl ní gúúsù àti ìlà oòrùn.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]