Jump to content

Gabriel Igbinedion

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Olóyè Gabriel Osawaru Igbinedion (ọjọ́ìbí September 11, 1934) ni oníṣòwò àti oníjóyè ará Nàìjíríà láti ìlú Ọkadá ní Ìpínlẹ̀ Ẹdó. Òhun ni ó wà lórí oyè gẹ́gẹ́bí Esama ìlú Benin.