Gbemi Olateru-Olagbegi
Ìrísí
Gbemi Olateru Olagbegi | |
---|---|
ni odun 2019 | |
Ọjọ́ìbí | Gbemi Olateru Olagbegi 18 Oṣù Keje 1984 Surulere, Èkó, Nàìjíríà |
Iléẹ̀kọ́ gíga |
|
Iṣẹ́ | Media personality |
Ìgbà iṣẹ́ | 2005–present |
Olólùfẹ́ | Femisoro Ajayi (m. 2018) |
Àwọn olùbátan | Bukunyi Olateru-Olagbegi |
Gbemi Olateru-Olagbegi jẹ́ olugbohunsafefe ọmọ órílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2]Gbemi ni ọmọ ọmọ ọlọ̀wọ́ ti ọ̀wọ̀; Sir Olateru-Olagbegi II KBE ti o wàjà.[3]
Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Gbemi Olateru-Olagbegi lọ́jọ́ kejidinlógún oṣù Keje ọdún 1984 si ile Banke ati Yemi Olateru-Olagbegi ni Ile-iwosan St. Nicholas, Lagos. Ó lọ sí Pampers Private School, Surulere, The Nigerian Navy Secondary School, Ojo laarin 1993 si 1997 lẹhinna o tẹsiwaju lọ ilé ẹkọ girama rẹ ni Queens College, Yaba nibiti o ti pari ni ọdun 2000. O gba BA ni awọn ibaraẹnisọrọ ni Oakland University, Rochester ati MSc. ni Media ati Communications lati Pan-Atlantic University,ni ilu Èkó.[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Gbemi Olateru-Olagbegi Goes Down Memory Lane as She Announces Her Last Day on Radio". BellaNaija. January 7, 2022. Retrieved May 22, 2022.
- ↑ "Gbemi Olateru-Olagbegi joins TNC Africa as co-founder". Pulse Nigeria. March 3, 2022. Retrieved May 22, 2022.
- ↑ "Gbemi Olateru-Olagbegi: Transmitting from Wireless to Boundless Opportunities". THISDAYLIVE. February 20, 2022. Retrieved May 22, 2022.
- ↑ Thomas-Odia, Ijeoma (February 19, 2022). "‘You have to put in top player work to be at the top’". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved May 22, 2022.