Jump to content

Gbenga Adefaye

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Editor-in-Chief/General Manager,Vangaurd Media(Newspapers)
Gbenga Adefaye
Ọjọ́ìbí1961-10-21
Ile-Ife
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigeria
Iṣẹ́Journalist
EmployerVanguard Media(Newspaper)
OrganizationIfe Development Union

Gbenga Adefaye jẹ́ Akọ̀ròyìn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, alákòóso àti ọ̀jọ̀gbọ́n ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn, pẹ̀lú ìrírí fún Ọgbọ̀n ọdún ní ilẹ̀-iṣẹ́ ìròyìn Nàìjíríà .[1][2][3] Òun ni olórí àwọn olóòtú fún Vanguard media (Ìwé ìròyìn) àti olórí ní Nigerian Institute of Journalism. Àti wí pé, ó ti fi ìgbà kan jẹ́ Ààrẹ fún Nigerian Guild of Editors (láti ọdún 2008 wọ 2013) àti a jẹ́ ọ̀kan lára ọmọ ẹgbẹ́ tó sẹ ìgbìmọ̀ aṣojú fún Fásítì Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà.[4][5]

Ó gba oyè ìparí ẹ̀kọ́ rẹ̀ nínú Iṣẹ́ Ìròyìn láti Fásitì Èkó, Nsukkaní ọdún 1984 àti oyè Másítàsì rẹ̀ ní Iṣẹ́ Ìròyìn ní Fáṣítì Èkó, Ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 1988[6]

Gbenga bẹ̀rẹ̀ igbese ayé rè gẹ́gẹ́ bíi onìròyìn pẹ̀lú the Nigerian Television Authority ní Ọdún 1985. Ó dára pọ mó the Vanguard Media ní ọdún 1986 àti ó sì dìde láti dí oniroyin/a kọ̀wé fún Feature Writer to Editorial Training Manager/Chief Sub-editor and ó si jẹ́ àwọn tó tún ìwé àti agbarijo adarí tí ilé ìṣe Vanguard (ìwé ìròyìn). Ní àfikún, Mr. Gbenga Adefaye wọn yán láti sì àwọn ẹ̀gbẹ́ the Provost of the Nigerian Institute of Journalism, pẹ̀lú àfihàn láti September 1, 2020 pẹ̀lú àwọn the Governing council of the institute.

Gbenga jẹ́ igbá-kejì arẹ́, Ife Development Board (IDB) àti Alága tí àwùjọ Ile-Ife.

  • Ó dá ilé ìṣe Radio Studio project- PEN RADIO àti ó ṣe olùṣọ́ igbohunsafefe ìwé àṣẹ láti the Nigerian Broadcasting Commission fún the Nigerian Institute of Journalism.
  • O dá He established the partnership between the Nigerian Guild of Editors and the Pan-Atlantic University, School of Media & Communications and, also started the groundwork for the Editors House in Lagos state.
  • Gbenga rallied notable Nigerian statesmen that insulated the nomination and installation of Ooni Ogunwusi Ojaja II in Osun state.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Ooni of Ife greets Vanguard's GM, Adefaye, at 60". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-24. Retrieved 2022-04-11. 
  2. "Reviewers’ introduction to Gbenga Adefaye: The media man @ 60". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-25. Retrieved 2022-04-11. 
  3. "Adefaye: Brother, buddy and tutor with a good heart, By Steve Ayorinde" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-27. Retrieved 2022-04-11. 
  4. "Adefaye returns as NGE president". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2011-01-15. Retrieved 2022-04-11. 
  5. "NewsLodge Latest "News in Nigeria" & Jobs update" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-04. Retrieved 2022-04-11. 
  6. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0