Georg Ohm
Ìrísí
Georg Simon Ohm | |
---|---|
Ìbí | Erlangen, Germany | 16 Oṣù Kẹta 1789
Aláìsí | 6 July 1854 Munich, Germany | (ọmọ ọdún 65)
Ibùgbé | Germany |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | German |
Pápá | Physics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Munich |
Ibi ẹ̀kọ́ | University of Erlangen |
Doctoral advisor | Karl Christian von Langsdorf |
Ó gbajúmọ̀ fún | Ohm's law Ohm's phase law Ohm's acoustic law |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Copley Medal (1841) |
Georg Simon Ohm (16 March 1789 – 6 July 1854) je asefisiksi ara Jemani. Gege bi oluko ni ile-eko agba, Ohm bere iwadi re pelu ahamo elektrokemika to sese je didawaye, ti ara Italia Oloye Alessandro Volta dawaye. Pelu awon irin-ise to da fun ra re, Ohm wadaju pe iseepin taara wa larin iyato alagbara (potential difference tabi voltage ni èdè Gẹ̀ẹ́sì) to je mimulo rekoja opa agbena kan ati iwo onitanna to waye. Ibasepo yi lamo loni si Ofin Ohm.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |