George Oguntade

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
George Oguntade
Ọjọ́ìbíGeorge Adesola Oguntade
Oṣù Kẹta 10, 1940 (1940-03-10) (ọmọ ọdún 81)
Epe, Lagos State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́Jurist
Ìgbà iṣẹ́1966 – 2010
Olólùfẹ́Modupe Oguntade[1]

George Adesola Oguntade (CFR, CON) (a bi ni ojo kewa, osu keta odun, 1940), je adajo agba ti o ti feyinti ni Ilé-ẹjọ́ Gígajùlọ ilẹ̀ Nàìjíríà Supreme Court of Nigeria laarin May 19, 2004 si May 10, 2010.[2][3]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]