Godwin Obaseki
Appearance
Godwin Obaseki | |
---|---|
Obaseki ni ọdún 2018 | |
Gómìnà ìkẹwà tí ìpínlẹ̀ Edo | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga Ọ́jọ́ ìkejìla Bèlu, 2016 | |
Deputy | Philip Shaibu |
Asíwájú | Adams Oshiomhole |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Godwin Nogheghase Obaseki Àdàkọ:Ọjọ́ ìbí àti ọjó orí Ìlú Benin, Ìpínlẹ̀ Edo, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nàìjíríànù |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People's Democratic Party (PDP) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Betsy Bene Obaseki |
Àwọn òbí | Ogbeni Roland Obaseki Stella Osarhiere Gbinigie |
Alma mater | Eghosa Grammar School ní Ìlú Benin University of Ibadan Columbia University Pace University |
Website | godwinobaseki.com |
Godwin Nogheghase Obaseki (Ọjọ́ ìbí: 1 Agẹmọ, 1957, ní Ilu Benin, Nigeria [1] ) jẹ́ olóṣèlú àti oníṣòwò kan ní ìlú Naijiria to sì jẹ Gómìnà Ipinle Edo àtọwò. Wọ́n gbé ìpò gómíná fun ní ọjó ìkejìla, Bèlu, 2016 ní. Oun lo jẹ́ Olóyè Edo State Economic and Strategy Team látọwọ́ gómìnà ìṣáájú, Adams Oshiomole, ní òṣù Erẹ́nà, l ọdún 2009.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2019-12-26. Retrieved 2019-12-13.