Jump to content

Gored gored

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gored gored plate, July 2019
Gored gored on top of injera

Gored gored (am) (Oromo: gurguddaa) jẹ́ ẹran màálù tí wọ́n ń jẹ ní Ethiopia. Nídà kejì, kitfo jẹ́ ẹran tí wọ́n fi sínú èròjà ìsebẹ̀ lóríṣiríṣi.[1] Bí i kitfo, ó gbajúmọ̀ gan-an, wọ́n sì mu gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ orílẹ̀-èdè náà.[2] It is often served with mitmita (a powdered seasoning mix) and awaze (oríṣi mọ́sítáàdì àti ata kan).[3]

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a máa ń fi oúnjẹ náà wé kitfo, a kìí jẹ gored gored lẹ́yìn tí a bá ti fi bọ́tà àti àwọn èròjà amọ́bẹ̀dùn kun. A máa ń fi jẹ injera, awaze, àti lemon wedges.

Ní ọ̀pọ̀ ìgbà, a máa ń fi ọ̀rá kalẹ̀ sí ara ẹran kí ó baà lè jẹ́ jíjẹ pọ̀ mọ. A lè dá Gored gored nìkan wà gẹ́gẹ́ bíi oúnjẹ, a sì lè wà á pẹ̀lú àkópọ̀ àwọn èròjà tí a dárúkọ lókè yìí, a lè jẹ́ pẹ̀lú àwọn oúnjẹ mìíràn fún oúnjẹ alẹ́, pàápàá ní àkókò ayẹyẹ.[4]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. EthioNetworks.com. "Ethiopian Gored Gored". Ethiopianrestaurant.com. Archived from the original on 2012-07-29. Retrieved 2011-12-13.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. KimHo. "Axum Ethiopian Restaurant | I'm Only Here for the Food!". Imonlyhereforthefood.com. Archived from the original on 2010-02-18. Retrieved 2011-12-13.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Lonely Planet (1 September 2017). Lonely Planet Ethiopia & Djibouti. Lonely Planet. pp. 612–. ISBN 978-1-78701-191-5. https://books.google.com/books?id=grkyDwAAQBAJ&pg=PT612. 
  4. "Gored gored | Traditional Beef Dish From Ethiopia | TasteAtlas". www.tasteatlas.com. Retrieved 2022-10-28.