Jump to content

Hamisu Ibrahim Kubau

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Hamisu Ibrahim Kubau je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà . Ó sìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ kan tó ń ṣojú ẹ̀ka Ikara/Kubau ni Ilé Awọn Aṣoju ṣòfin. Wọ́n bil ní ọjọ́ kẹtàdínlógún osu kẹrin ọdún 1975, o wa láti Ìpínlẹ̀ Kaduna . Won dibo yàn si ile ìgbìmò aṣòfin lódun 2019 lábé ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC). [1] [2]