Hamza Idris
Ìrísí
Hamza Idris | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Keje 1972 Jos, Plateau State |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Maiduguri |
Iṣẹ́ | Journalist |
Organization | Media Trust, Publishers of Daily Trust Newspapers |
Title | Editor Daily Trust Newspapers |
Hamza Idris (tí a bí ní 27 July ọdún 1972) jẹ́ akọ̀ròyìn àti asàtúnse ilé-isé ìwé ìròyìn Nigeria's Daily Trust Newspapers,[1][2] òkàn lára àwọn ilé-isé ìwé ìròyìn tó ń síwájú ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni aláàmójútó ipò mèta ní ilé isẹ́ ìwé ìròyín tó ti ń sisẹ́: Daily Trust, Daily Trust Saturday and Daily Trust on Sunday.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.pressreader.com/nigeria/daily-trust/20190902/281552292534410. Retrieved 2020-12-28 – via PressReader. Missing or empty
|title=
(help) - ↑ Wakili, Isiaka (2019-09-01). "Daily Trust makes new appointments". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-12-28.
- ↑ "Dailytrust News, Sports and Business, Politics | Dailytrust". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-17.