Jump to content

Hanks Anuku

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Hanks Anuku
Ọjọ́ìbíỌjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1960
Ibadan
Iléẹ̀kọ́ gígaAuchi Polytechnic
Iṣẹ́òṣèré

Hanks Anuku tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 1960 (12 May 1960)[1][2] jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó máa ń kópa nínú sinimá àgbéléwò èdè Gẹ̀ẹ́sì àti Ìgbò [3][4] As of 2017, Anuku was naturalized and became a Ghanaian.[5]

Anuku lọ sí ilé-ìwé Loyola College, ní ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí ní ilé-ìwé Auchi Polytechnic in 1981,[6] and he was born 1960 in Ibadan.[2]

Àtòjọ àwọn sinimá-àgbéléwò tí ó ti kópa

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Broad Daylight (2001)
  • Bitter Honey (2005)
  • The Captor (2006)
  • Men on Hard Way (2007)
  • Fools on the Run(2007)
  • Desperate Ambition(2006)
  • My Love
  • Wanted Alive
  • Rambo

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]