Henrietta Kosoko
Ìrísí
Henrietta Kosoko | |
---|---|
Iṣẹ́ | òṣèré |
Olólùfẹ́ | Jídé Kòsọ́kọ́ |
Henrietta Kòsọ́kọ́ jẹ́ òṣèré Nollywood.[1] Ó di ìlúmọ̀ọ́ká ní ọdún 1995 lẹ́hìn tí ó kópa nínu àwon fíìmù Nollywood bíi Ọnọmẹ́ àti Ọmọladé . Òun ni ìyàwó gbajúgbajà òṣèré Jídé Kòsọ́kọ́.[2][3][4][5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.informationng.com/2016/06/15-things-you-may-not-know-about-henrietta-kosoko.html/amp
- ↑ "Nollywood actress, wife of Jide Kosoko, Henrietta Kosoko is dead - Vanguard News" (in en-US). Vanguard News. 2016-06-06. https://www.vanguardngr.com/2016/06/nollywood-actress-wife-jide-kosoko-henrietta-kosoko-dead/amp/.
- ↑ "15 Things You May Not Know About Henrietta Kosoko - INFORMATION NIGERIA" (in en-US). INFORMATION NIGERIA. 2016-06-06. http://www.informationng.com/2016/06/15-things-you-may-not-know-about-henrietta-kosoko.html.
- ↑ "Nigeria: Top 8 Nollywood Stars That Died In 2016 - Nigerian Bulletin - Trending News". Nigerian Bulletin - Trending News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-08-28.
- ↑ "10 Stunning Photos of Henrietta Kosoko in Her Fifties - INFORMATION NIGERIA" (in en-US). INFORMATION NIGERIA. 2016-06-07. http://www.informationng.com/2016/06/10-stunning-photos-of-henrietta-kosoko-in-her-fifties.html.