Herring smelt

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Herring smelt
Argentina sphyraena
Scientific classification
Kingdom: Animalia
Phylum: Chordata
Class: Actinopterygii
Order: Argentiniformes
Family: Argentinidae
Bonaparte, 1838
Genera

Argentina
Glossanodon

Herring smelts tàbí àwọn argentine jẹ́ ẹbí, Argentinidae, ti òkún smelts. Ìrísí wọn dàbí ti smelts (ẹbí Osmeridae) ṣùgbọ́n ẹnu won kéré díẹ̀.

Oríṣi àwọn  ẹ̀yà ìdílé Argentina, ti Geological Museum, Copenhagen

Wọ́n maa ń rí wọ́n nínú òkun káàkiri gbogbo agbayé. Wọ́n jẹ́ ẹja kékeré, tí wọ́n maa ń dàgbà tó bí  25 centimetres (9.8 in)  ní gígùn, yàtọ̀ sí argentine títóbi, Argentina silus, t́ ó maa ń tó bíi 70 centimetres (28 in).

Wọ́n maa ń kó ara wọn jẹ̀ lọ́pọ̀ tuutu súmọ̀ ìsàlẹ̀ òkun, wọ́n maa ń jẹ plankton, krill, amphipods, cephalopods, chaetognaths kékeré, àti ctenophores.

Wọ́n maa ń pa wọ́n fún títa tí wọ́n sì maa ń ṣètò wọn fún jílẹ.

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Froese, Rainer, and Daniel Pauly, eds. (2012). "Argentinidae" in FishBase. February 2012 version.