Hogan Bassey

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Hogan "Kid" Bassey (1932-06-03 - 1998-01-26) je omo ile Naijiria. Oruko ti a so ni Okun Asuguo Bassey. Ní ọdún 1952, ọwọ́ Nàìjíríà kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ Hogan Bassey di world featherweight Champion ní ìlú òyìnbó.