Jump to content

Hubert Ingraham

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Hubert Ingraham
2nd Prime Minister of the Bahamas
In office
4 May 2007 – 8 May 2012
MonarchElizabeth II
Governor GeneralA.D. Hanna
Sir Arthur Foulkes
DeputyBrent Symonette
AsíwájúPerry Christie
Arọ́pòPerry Christie
In office
21 August 1992 – 3 May 2002
MonarchElizabeth II
Governor GeneralSir Clifford Darling
Sir Orville Turnquest
Dame Ivy Dumont
AsíwájúSir Lynden Pindling
Arọ́pòPerry Christie
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kẹjọ 1947 (1947-08-04) (ọmọ ọdún 77)
Pine Ridge, Bahamas
Ẹgbẹ́ olóṣèlúProgressive Liberal Party (1970s–1987)
Independent (1987–1990)
Free National Movement (1990–present)
(Àwọn) olólùfẹ́Delores Miller

Hubert Alexander Ingraham (ọjọ́ìbí 1947) ni Alákóso Àgbà ilẹ̀ àwọn Bàhámà tẹ́lẹ̀. Ó kọ́kọ́ bọ́sí ipò Alákóso Àgbà láti August 1992 dé May 2002 ati láti 2007 de 2012. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ọ̀ṣèlú Free National Movement Party (FNM).