Human Rights Watch
Ìrísí
Irú | Non-profit NGO |
---|---|
Dídásílẹ̀ ní | 1978 under the name Helsinki Watch Adopted current name in 1988.[1] |
Ibùjókòó | New York City |
Òṣìṣẹ́ | Kenneth Roth, Executive Director |
Method | Human rights, Activism |
Ibitàkun | http://www.hrw.org |
Human Rights Watch je agbajo aije ti ijoba kariaye kan to un sewadi ati akitiyan fun awon eto omoniyan. Ibujoko re wa ni ilu New York o si ni awon ibi-ise ni Berlin, Brussels, Chicago, Geneva, Johannesburg, London, Los Angeles, Moscow, Paris, San Francisco, Tokyo, Toronto, ati Washington D.C.[2]
Itan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Human Rights Watch je didasile labe oruko Helsinki Watch ni odun 1978 lati mojuto bi orile-ede tele Isokan Sofieti se un tele Awon Ipinnu Helsinki.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Our History". Human Rights Watch. Retrieved 2009-07-23.
- ↑ "Frequently Asked Questions". Human Rights Watch. Retrieved 2009-07-23.