Hypertext
Hypertext tabi Ikokoja je iko lori komputa tabi ohun ero afinasise miran, pelu awon itokasi (ijapokoja) si awon iko miran ti olukawe le lo kiakia, boya pelu klik ekute tabi tite botini lori patako botini. Leyin pe oun fihan iko, hypertext tun le ni tabili, aworan ati awon ohun ifilo miran. Hypertext ni ajoyumo abe to unsetumo opo World Wide Web, to mu ko je ko rorun lati lo ati lati pin ifitonileti lori Internet.[1]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ "Internet legal definition of Internet". West's Encyclopedia of American Law, edition 2. Free Online Law Dictionary. July 15, 2009. Retrieved November 25, 2008.