Ibà Zika
Ibà Zika | |
---|---|
Ìpínsọ́wọ̀ àti àwọn òkunfà ìta | |
ICD/CIM-10 | U06.9 Code change from 21 December 2015 U06.9 Code change from 21 December 2015 |
ICD/CIM-9 | 066.3 066.3 |
Ibà Zika, (àrùn Ibà Zika) tí a túnmọ̀sí àrùn àkóràn Zika, jẹ́ àìsàn tí Àkóràn Zikańfà.[1] àwọn ààmì farajọ ti ibà dengue.[1] Ní àwọn ọ̀pọ̀ ìgbà (60–80%) ni kòní àwọn ààmì.[2] Bí àwọn ààmì báwà wọ́n sábà maa ńjẹ́ ibà, ẹyin ojú pípọ́n, àwọ́ká, èfọrí, àti maculopapular rash.[3][1] Àwọn ààmì lápapọ̀ kòpọ̀ bẹ́ẹ̀ni wọn kìí ju ọjọ́ méje lọ.[4] Kòíti sí ikú lákókò àkorán àkọkọ́ ní ọdún 2015.[2] Àkóràn wáyé láti ara Guillain–Barré syndrome.[2]
Okùnfà àti ìwádìí aisàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ibà Zika maa ńràn nípa ìbùjẹ ti ẹ̀fọn ti irúfẹ́ Aedes.[4] Ó tún ṣeéṣe láti ràn nípa ìbálòpọ̀ àti ìfa ẹjẹ̀ sára.[4] Àrùn yíì lèràn láti ìyá sí ọmọ-inú oyún àti okùnfà microcephaly.[1][2] Ìwádìí àìsàn ni nípa àyẹ̀wò ẹ̀jẹ̀, itọ́, tàbí itọ́ fún àkóràn RNA nígbà tí ènìyàn ba ṣàìsàn.[4][1]
Ìdẹ́kun àti ìtọjú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lára ìdẹ́kun ni díndín àwọn ìbújẹ ẹ̀fọn kù ní àwọn agbègbè tí àrùn ti wáyé.[4] Lára ipá ni lílo ogùn apẹ̀fọn, bíbo ọ̀pọ̀ ara pẹ̀lú aṣọ, àwọ̀n apẹ̀fọn, àti rírí pé kòsí omi adágún nítorí ibí ni ẹ̀fọn ti ń bísi.[1] Kòsí oogùn ìwosàn kan gbòógì.[4] Àwọn òṣìṣé ìlera Bùràsílí gbaninímọ̀ràn ní ọdún 2015 pé kí àwọn òbí ronú mímú oyún kúrò nítorí ìtànkálẹ̀ asì gbaninímọ̀ràn pé àwọn aláboyún kò gbọdọ̀ rin ìrìn-ajò lọ ibi tí àjàkálẹ̀ àrùn wà.[5][4] Níwọ̀n ìgbà tí kòsí ìtọjú kan pàtó, paracetamol (acetaminophen) lèṣe ìrànwọ́ pẹ̀lú àwọn aamì.[4] Admission to the hospital is rarely needed.[2]
Ìtàn àti ìmọ̀ nípa ààrùn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkóràn to ń ṣòkunfà ààrùn yíì ni akọ́kọ́ yàsọ́tọ̀ ní ọdún 1947.[6] Àkọ́kọ́ kọsílẹ̀ nípa àtànkálẹ̀ rẹ̀ láàrin àwọn ènìyàn wáyé ní ọdún 2007 ní Ìjọba Ìpínlẹ̀ Micronesia.[4] Ní oṣù kiní ọdún 2016 ni ààrùn yíì wáyé ní àwọn ẹkùn ogún nílu ti Amẹ́ríkà.[4] A túnmọ̀ pé ó wáyé ni Áfíríkà, Áṣíà, àti ní Etíkun.[1] Nítorí àjàkálẹ̀ tó bẹ̀rẹ̀ ní Bùràsílì ní ọdún 2015, Àjọ Ìgbìmọ̀ Àgbayé kéde rẹ̀ bíi Ìlera Àwujọ Pàjawírì tí ó Kan Gbogbo Àgbayé ní Oṣù kejì ọdún 2016.[7]
==Àwọn Atọ́ka==
- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 1.5 1.6 "Zika virus". WHO. January 2016. Retrieved 3 February 2016.
- ↑ 2.0 2.1 2.2 2.3 2.4 "Factsheet for health professionals". ecdc.europa.eu. Retrieved 22 December 2015.
- ↑ Musso, D.; Nilles, E.J.; Cao-Lormeau, V.-M. (2014). "Rapid spread of emerging Zika virus in the Pacific area". Clinical Microbiology and Infection 20 (10): O595–6. doi:10.1111/1469-0691.12707. PMID 24909208. http://linkinghub.elsevier.com/retrieve/pii/S1198743X1465391X.
- ↑ 4.00 4.01 4.02 4.03 4.04 4.05 4.06 4.07 4.08 4.09 Chen, LH; Hamer, DH (2 February 2016). "Zika Virus: Rapid Spread in the Western Hemisphere.". Annals of internal medicine. PMID 26832396. http://annals.org/article.aspx?articleid=2486362.
- ↑ "Brazil warns against pregnancy due to spreading virus - CNN.com". CNN. Retrieved 24 December 2015.
- ↑ Haddow, AD; Schuh, AJ; Yasuda, CY; Kasper, MR; Heang, V; Huy, R; Guzman, H; Tesh, RB et al. (2012). "Genetic characterization of Zika virus strains: geographic expansion of the Asian lineage.". PLoS neglected tropical diseases 6 (2): e1477. PMID 22389730.
- ↑ "WHO Director-General summarizes the outcome of the Emergency Committee regarding clusters of microcephaly and Guillain-Barré syndrome". WHO. 1 February 2016. Retrieved 3 February 2016.