Jump to content

Ibrahim Tanko

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Muhammad Tanko

Chief Justice of Nigeria
In office
25 January 2019 – 27 June 2022
AsíwájúWalter Samuel Nkanu Onnoghen
Arọ́pòOlukayode Ariwoola
Justice of the Supreme Court of Nigeria
In office
7 January 2007 – 27 June 2022
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Ibrahim Muhammad Tanko

31 Oṣù Kejìlá 1953 (1953-12-31) (ọmọ ọdún 70)
Giade, Northern Region, British Nigeria (now Giade, Bauchi State, Nigeria)

Ibrahim Muhammad Tanko [1](tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n, oṣù kejìlá, ọdún 1953) jẹ́ adájọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó sìn ní ilé-ẹjọ́ tí ó ga jù lọ láti ọdún 2006 wọ ọdún 2022, àti bíi adájọ́ àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà láti ọdún 2019 títí ó fi fìwé ìfipòsílẹ̀ ráńṣẹ́ ní oṣù kẹfà ọdún 2022 nítorí àìlera rẹ̀. [2][3][4][5] Ó fìgbà kan jẹ́ adájọ́ ní ilé-ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn.[6][7]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayẹ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tanko jẹ́ ọmọ Fulani tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n, oṣù kejìlá, ọdún 1953 ní Doguwa-Giade tó jẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ kan ní Ìpínlẹ̀ Bauchi, tó wà ní apá Àríwá ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó lọ sí ilé-ìwé gírámà ti ìjọba ni ìlú Azare, níbi tí ó ti gboyè WAEC ní ọdún 1973 kí ó tó lọ sí Fáṣítì Ahmadu Bello níbi tí ó ti gboyè LL.B. nínú ẹ̀kọ́ òfin Islam ní ọdún 1980. Ó padà gboyè LL.M. àti Ph.D. nínú ẹ̀kọ́ òfin ní Fáṣítì kan náà ní ọdún 1985 àti 1998 bákan náà.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "FULL LIST: Okonjo-Iweala, Abba Kyari... FG nominates 437 persons for national honours". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-10-02. Retrieved 2022-10-11. 
  2. Nda-Isaiah, Jonathan (2022-06-27). "BREAKING: President Buhari Swears In Justice Ariwoola As Acting CJN" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-28. 
  3. "Justice Tanko Muhammad Resigns As CJN". Channels Television. Retrieved 2022-06-27. 
  4. "Chief Justice of the Supreme Court of Nigeria". 
  5. "The Nation Newspaper - Latest Nigeria news update" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-07. Retrieved 2022-06-27. 
  6. Tobi Adeyeye. "CJN removes 2 Supreme Court justices off election petition tribunal". The Herald. Archived from the original on 2016-03-04. Retrieved 2022-10-13. 
  7. "Service chiefs, Soun, Osemawe, Oyegun, Omosexy, 292 others on national honours' list". tribune.com.ng. Archived from the original on 18 May 2015. Retrieved 30 April 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)