Idowu Sofola
Ìrísí
Idowu Sofola | |
---|---|
President of the Nigerian Bar Association | |
In office 1980–1982 | |
Chairman of the Nigerian Body of Benchers | |
In office March 30, 2012 – 2013 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Ikenne, Ogun State, Nigeria | 29 Oṣù Kẹ̀sán 1934
Aláìsí | 23 March 2018 | (ọmọ ọdún 83)
Olóyè Idowu Sofola, SAN, MON (29 September 1934 – 23 March 2018)[1] fìgbà kan jé agbẹjọ́rò, adájọ́ àti Ààrẹ Nigerian Bar Association. Ó fi ìgbà kan jé alága Nigerian Body of Benchers.[2]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Olóyè Idowu ní September 1934 sí ìlú Ikenne, èyí tó jẹ́ ìlú kan ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní apá Gúúsù mọ́ Ìwọ̀-Oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà.[3]
Ìjẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Nigerian Bar Association
- International Bar Association
- Nigerian Body of Benchers
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Odigwe, Emmanuel (23 March 2018). "Former President Of The Nigeria Bar Association, Idowu Sofola, Dies At 84". theeagleonline.com. Archived from the original on 24 March 2018. Retrieved 24 March 2018.
- ↑ "CJN steps down as Chairman Body of Benchers, Sofola takes over". Vanguard News. Retrieved 24 April 2015.
- ↑ "Remembering legal luminary: Idowu Abdulfatai Adebayo Sofola (SAN) (1934 - 2018)". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-30. Retrieved 2022-03-10.