Idris Akọkọ ti Morocco

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Idris I ibn Abd Allah
إدريس بن عبد الله
Emir of Morocco
Reign 788–791
Predecessor None
Successor Idris II of Morocco
Spouse Kenza al-Awrabiya
Issue
Idris II of Morocco
Full name
Idris ibn Abd Allah ibn al-Hasan ibn al-Hasan ibn Ali
Father Abd Allah al-Mahd
Mother Atika bint Abd al-Malik
Born Unknown
Arabian Peninsula
Died 791
Volubilis
Burial Moulay Idriss Zerhoun

Idris (akọkọ) ibn Abd Allah (Èdè larubawa: إدريس بن عبد الله, Èdè Roman: Idrīs ibn ʿAbd Allāh) ni a tumọ si Idris Agba (Èdè Larubawa: إدريس الأكبر, Èdè Roman: Idrīs al-Akbar), (d. 791) jẹ ara larubawa Hasanid Sharif ati oludari Idrisid dynasty ti northern Morocco pẹlu ajọṣèpọ ẹya Berba ti Awraba, lẹyin ti wọn sa ni Hejaz latari ogun ti Fakhkh.

Igbesi Àye Idris Akọkọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Idris akọkọ jẹ ọmọ ọmọ Hasan, ọmọ Fatima ati Ali, ọmọ ọmọ anọbi Muhammad. A bisi ilẹ Arabia. Idris fẹ Kenza ti Awraba tosibi ọmọ kan, Idris keji ti Morocco. Eyi lo mu idasilẹ Idrisid dynasty, ipinlẹ musulumi kẹrim ni Morocco lẹyin Nekor (710–1019), Barghawata (744–1058), ati Midrar (757–976).

The Mausoleum of Idris I (green roofed structure, lower left) in Moulay Idriss

Idris I jagun ba awọn apa ibi to tobi ni ariwa ilẹ Morocco to si da agbegbe ti Fez silẹ. Ni ọdun 1789 AD, Idris jagun ba Tlemcen lati Sufrite Ifranid Abu Qurra eyi lo mu ki Abbasid caliph Harun al-Rashid gbẹsan to si awọn agbenipa si. Idris akọkọ ku ni ọdun 1791 ni Walīlī. Idris keji, ọmọ rẹ ni a bini óṣu melo kan sẹyin ti Awraba si re dagba ni abẹ̀ adele baba rẹ Rashid. Ni ọdun 1808, o kuro ni Walīlī lọ si Fes, nigba idari rẹ̀ (791–828), o sọ Fez di ilu nla

Wọn si Idris akọkọ si oke kan ti ko jina si Walīlī. Tubu rẹ gun lọsi Abulè kan ti a n pè ni Moulay Idriss Zerhoun. Ilè ẹsin Zawiya ni agbegbe mausoleum gboro ni bẹ fun aimoye ọdun to si pada di ilè ẹsin pataki ni ilẹ Morocco.

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]