Idris elba
Idris Elba Àdàkọ:Post-nominals | |
---|---|
Elba ní ọdún 2024 | |
Ọjọ́ìbí | Idrissa Akuna Elba 6 Oṣù Kẹ̀sán 1972 Hackney, London, England |
Orúkọ míràn |
|
Ọmọ orílẹ̀-èdè |
|
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1994–present |
Works | |
Olólùfẹ́ |
|
Àwọn ọmọ | 2 |
Awards | Full list |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments |
|
Labels |
|
Associated acts | Lime Cordiale |
Idrissa Akuna Elba ( /ˈɪdrᵻs/ IH-driss; í6a bí ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹsàn-án ọdún 1972) jẹ́ òṣeré àti akọrin ọmọ orílẹ̀ ède Gẹ̀ẹ́sì. Óokọ́ nípa orin ní National Youth Music Theatre ní London, ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínú Stringer Bell, eré HBO, The Wire (2002–2004), John Luther nínú eré BBC One Luther (2010–2019), àti gẹ́gẹ́ bi Nelson Mandela nínú eré Mandela: Long Walk to Freedom (2013). Fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Luther, wọn yàn án fún àmì ẹyẹ Golden Globe Award for Best Actor àti Primetime Emmy Award for Outstanding Lead Actor.[3][4][5]
Elba kópa nínú àwọn eré bi American Gangster (2007), Obsessed (2009) àti Prometheus (2012). Ó kó ipa Heimdall nínú Marvel Cinematic Universe (MCU), bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú Thor (2011), àti gẹ́gẹ́ bi Bloodsport nínú The Suicide Squad (2021). Ó tún ṣeré nínú eré Pacific Rim (2013), Beasts of No Nation (2015), èyí tí ó mú kí wọ́n yàn án fún àmì ẹyẹ Golden Globe àti BAFTA. Ọkàn nínú àwọn nǹkan tí ó tún gbajúmọ̀ sí ni ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ Rufus Buck nínú The Harder They Fall (2021).
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Yuan, Jada (8 June 2012). "Idris Elba on Prometheus, Learning to Box, and His Party House". vulture.com. https://www.vulture.com/2012/06/idris-elba-prometheus-interview.html.
- ↑ "Idris Elba given Sierra Leone citizenship". BBC News. 20 December 2019. https://www.bbc.com/news/world-africa-50871307.
- ↑ Lowry, Brian (10 July 2014). "Emmy Nominations 2014 — Full List: 66th Primetime Emmys Nominees". Variety. https://variety.com/2014/tv/news/emmy-nominations-2014-list-emmys-nominees-1201260236/. Retrieved 28 January 2015.
- ↑ "Wire actor Elba joins BBC drama". BBC News. 4 September 2009. http://news.bbc.co.uk/2/hi/entertainment/8237924.stm.
- ↑ "Idris Elba". Prince's Trust. Retrieved 16 March 2023.