Ilé iṣẹ Rádíò ìpínlẹ̀ Ogùn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
OGBC
Broadcast area Ogun State
Frequency FM: 90.5
First air date 2 Oṣù Kejì 1977 (1977-02-02)
Format News, talk, and drama
Language(s) English
Owner Ogun State Government
Webcast FM
Website Official website

Ilé iṣẹ́ Rédíò ìpínlẹ̀ Ogùn tí ìgé kúrú rẹ̀ jẹ́ OGBC jẹ́ ilé iṣẹ́ ìjọb ti Ìpínlẹ̀ Ògùn

[1] Olú ilé iṣẹ́ náà fìdí kalẹ̀ sí Ìbarà ní ìlú Abẹ́òkútatí ó jẹ́ olú ìl7 ìpínlẹ̀ Ògun ní apá ìwọ̀ Oòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà . Orì ìkànì 90.5FM àti 92.80 ni wọ́n ti ń gbóhùn sáfẹ́fẹ́. Wọ́n dá ilé iṣẹ́ náà kalẹ̀ ní ojọ́ Kejì oṣù Kejì, ọdún 1977 (February 2, 1977) gẹ́gẹ́ bí ilé isẹ́ rédíò ti ìjọba.[2]

Ẹ tún le wo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ogun State Television

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Empty citation (help) 
  2. Empty citation (help)