Ile Ominira

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ilẹ̀ Omínìra  jẹ́ ilé-iṣẹ́ alájà márùndínlọ́gbòn tí wà ní ìwọ̀ oòrùn Tafawa Balewa Square, ní Oníkan ní ìlú Èkó.[1]

Ìjọba orílẹ̀-èdè Britain ní ó ṣe ìdáwọ́lé yìí nípa kí ó lè ìjẹ́rísí òmìnira orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 1960.[2]

Ilé Òmìnira

Konkere ti won ti fi agbara kun ni won fi ko ile yi, inu ile yi ni ile olori ise olugbega wa nigba isakoso Babangida, awon eyan de mo bi Ile Olugbega. Ni odun 1993, awon apa kan ninu ile yi jona, lati igba ti isele yi ti sele ni won o toju ile yi daradara.

Awon itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]