Ini Ikpe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ini Ikpe
Ọjọ́ìbíIni Simon Ikpe
Akwa Ibom, Nigeria
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́2004 - Till Date
Olólùfẹ́Hon Joe Etukudo

Ini Ikpe jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ fíìmù rẹ̀ ní ọdún 2003, ó sì ti kópa nínu àwọn fíìmù tó lé ní ọgọ́rùn-ún láti ìgbà náà. Ní ọdún 2012, ó gba àmì-ẹ̀yẹ amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ òṣèré tí ó dára jùlọ fún ti ipa rẹ̀ nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Kokomma.[1] Eré Kokomma náà tún ní àwọn ìyẹ́sí mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ níbi ayẹyẹ 9th Africa Movie Academy Awards.[2]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ini Ikpe jẹ́ ẹ̀yà Ibibio láti Ìpínlẹ̀ Akwa Íbọm, Nàìjíríà. Olùkọ́ ilé-ìwé ni ìyá rẹ̀, bàbá rẹ̀ sì jẹ́ alàgbà ilé ìjọsìn kan. Òun ni àbílé kẹẹ̀rin nínu àwọn ọmọ mẹ́fa ti òbí rẹ̀. Ó lọ sí Cornelius Connely College tí ó wà ní ìlú Calabar fún ètò ẹ̀kọ̀ girama rẹ̀. Ó jẹ́ ọ̀rẹ́ pẹ̀lú Ini Ẹdó, lẹ́ni tí wọ́n dì jọ lọ sí ilé-ìwé kan náà. Ó wọ agbo eré ìdárayá nípasẹ̀ Ini Ẹdó àti Emem Isong tí wọ́n ṣe ọ̀rẹ́ rẹ̀.

Iṣẹ́ ìṣe rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ òṣèré rẹ̀ ní ọdún 2004 pẹ̀lú kíkópa nínu eré tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Yahoo Millionaire.

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Yahoo Millionaire
  • The Greatest Sacrifice
  • Kokomma
  • I'll Take My Chances

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. wọn
  2. tọ́k

Àwọn ìtakùn Ìjásóde[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]