Ire Aderinokun
Ire Aderinokun | |
---|---|
Ire Aderinokun | |
Ọjọ́ìbí | Lagos, Nigeria |
Ibùgbé | Lagos, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Bristol |
Iṣẹ́ | Website Developer |
Ire Adérìnókùn tí í ṣe ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jẹ́ front end developer àti Google developer expert.[1][2][3] Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ nílẹ̀ Nàìjíríà tí ó jẹ́ Google Developer Expert.[4][5][6][7]
Ìgbésí ayé àti ètò-èkó rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ire wá láti ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. A bí sínú ìdílé Tayo àti Mrs. Olunfunlola Aderinokun.[8]
Lẹ́yìn tó gba ìwé-ẹ̀rí ònípele àkọ́kọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó lọ sí University of Bristol níbi tó ti gboyè Bachelors degree nínú Experimental Psychology. Nígbà tó ń kẹ́kọ̀ọ́ láti gboyè masters degree nínú Law ní University of Bristol, Ìfẹ́ tó ní sí Computer Science ló mu lọ sí Codeacademy.[9][10]
Ire jẹ́ frontend developer àti user interface designer. Ire dá blog tí rẹ̀ sílẹ̀ lọ́dún 2015 tí ó pè ní bitsofcode, ibẹ̀ ló ti ń dá àwọn èèyàn tó nífẹ̀ẹ́ sí ìmọ̀ kọ̀m̀pútà lẹ́kọ̀ọ́.[11]
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ire jẹ́ Google Developer Expert tó ń ṣiṣẹ́ lórí front-end technologies HTML, CSS, àti Javascript.[12][13] Ire tún jẹ́ òǹkọ̀wé ní TechCabal. [14]
Ó ṣàmúwáyé ètò Frontstack, fún front-end engineering ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó sì tún bẹ̀rẹ̀ ètò scholarship kékeré kan láti fi rán àwọn obìnrin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kí wọ́n le lọ fún Udacity Nanodegree ní ẹ̀ka tó ní ṣe pẹ̀lú technology tó wùn wọ́n.[15][3] Ó tún jẹ́ ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ àti igbákejì ààrẹ fún Engineering of BuyCoins.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ire Aderinokun: The Inspiring Tech Queen". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-19. Archived from the original on 2020-08-07. Retrieved 2020-03-12.
- ↑ BellaNaija.com (2020-02-24). "These 5 Nigerian Women Are Crushing It in the Tech Space". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-12.
- ↑ 3.0 3.1 BellaNaija.com (2019-03-28). "From Software Engineers to Venture Capitalists & Policy Makers! These Tech Women had the AUDACITY to Pursue their Big Dreams". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-12.
- ↑ "Ire Aderinokun Is The First Nigerian Woman To Become Google Developer Expert". Women Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-09. Retrieved 2020-03-09.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Ajiboye, Tolu (2017-08-14). "Breaking the code: how women in Nigeria are changing the face of tech" (in en-GB). The Guardian. ISSN 0261-3077. https://www.theguardian.com/lifeandstyle/2017/aug/14/breaking-the-code-how-women-in-nigeria-are-changing-the-face-of-tech.
- ↑ "17 powerful women who have shaped Nigerian culture". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-06. Retrieved 2020-03-12.
- ↑ "Girl power in a tech world". The Africa Report.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-02. Retrieved 2020-03-12.
- ↑ "Ire Aderinokun Is The First Nigerian Woman To Become Google Developer Expert". Women Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-09. Retrieved 2020-03-12.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Women in Tech: Ire Aderinokun". townhall.hashnode.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-12.
- ↑ "Meet Ire Aderinokun, Nigeria's first female Google Developer Expert". Grafrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-03-05. Archived from the original on 2021-12-04. Retrieved 2020-03-12.
- ↑ "Tech Women Lagos" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-03-07. Retrieved 2020-03-12.
- ↑ "17 powerful women who have shaped Nigerian culture". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-06. Retrieved 2020-03-12.
- ↑ "The 10 most influential people in tech this year". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-12-13. Archived from the original on 2019-03-08. Retrieved 2020-03-12.
- ↑ "Ire Aderinokun". TechCabal (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-12.
- ↑ "Story of Ire Aderinokun - Enabling knowledge for all". Udacity (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-23. Retrieved 2020-03-12.