Isanraju

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìsanra púpọ̀ jẹ́ ipò ti òrá wà nínú ara tí ó sì lè mú ewu bá ara. A ma sọ pe ènìyàn sanra jù nígbà tí "atọ́ka ibi-ara"(tí àwon dókítà òyìnbó pè ní BMI) ju ọgbọ̀n(30) lọ nínú ara.[1] Isanra púpò kìí dédé wáyé lásán, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé isanra púpọ̀ jù lè fàá kí ọ̀rá ó dí àwọn fọ̀rán iṣan tí a mọ̀ sí ártìrì tí ó ń gbé ẹ̀jẹ̀ lọ bọ̀ sínú ọkàn ó dí, èyí sì lè fa àrùn ọkàn tàbí kí ọkàn ènìyàn ó ma ṣe ségesège.

Awọn okunfa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Jiini
  2. Igbesi aye
  3. Homonu
  4. Irúfẹ́ óúnje tí a ń jẹ

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Defining Adult Overweight and Obesity". Centers for Disease Control and Prevention (in Èdè Sípáníìṣì). 2021-06-07. Retrieved 2022-02-20.