Ishaq Sidi Ishaq
Ìrísí
Ishaq Sidi Ishaq | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ishaq Sidi Ishaq |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Bayero University Kano |
Iṣẹ́ | Actor,[1] film maker, producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1996–present |
Notable credit(s) | Best known for directing Wasila |
Olólùfẹ́ | Naseeba Usman (m. 2016) [2] |
Ishaq Sidi Ishaq jẹ́ òṣèrékùnrin ti ilẹ̀ Nàìjíríà, olùdarí, akọ̀ròyìn fíìmù/eré orí-ìtàge, aṣagbátẹrù fíìmù,[3] òṣèré, àti òǹkọ̀wé tí ó jẹ́ aṣáájú-ọ̀nà nínú fíìmù ilẹ̀ Hausa, ní Nàìjíríà.[4] Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí Olùrànlọ́wọ́ Àkànṣe Agba ti Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kano sí Gómìnà Aláṣẹ ti ìpínlẹ̀ Kano lórí àwọn ilé-iṣẹ́ oníṣẹ̀-ọnà ní May 2021.[5]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ IMDb. "Ishaq Sidi Ishaq – Biography – IMDb". IMDb. Retrieved 2022-09-23.
- ↑ BBC Hausa News (26 February 2016). "An daura auren Ishaq Sidi Ishaq – BBC Hausa News". BBC Hausa News. Retrieved 2022-09-23.
- ↑ Daily Trust (7 March 2015). "My Journey As A Filmmaker – Ishaq Sidi Ishaq – Daily Trust". Daily Trust. Retrieved 2022-09-23.
- ↑ Stage32. "Ishaq Sidi Ishaq – Ishaq's Bio, Credits, Award… – Stage 32". Stage32. Retrieved 2022-09-23.
- ↑ Aisha Khalid (2 June 2021). "Ganduje ya nada Daraktan Kannywood Ishaq Sidi Ishaq mai bashi shawara". Legit. Retrieved 2022-09-23.