ISO 3166

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Iso 3166)
Jump to navigation Jump to search

ISO 3166 je apa meta opagun amioro, fun agbegbe lati se amioro fun awon orile-ede, awon agbegbe to ba le won ati ipin apa won, ti Àgbájọ Káríayé fún Ìṣọ̀págun tesiwejade. Oruko re gangan ni Awon amioro fun isoju fun awon oruko orile-ede ati ipinlabe won.

Awon apa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]