Jùmọ̀kẹ́ Ọdẹ́tọ́lá
Ìrísí
Ọlájùmọ̀lẹ́ Ọdẹ́tọ́lá | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | October 16 |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Ajayi Crowther University |
Iṣẹ́ | Filmmaker |
Ọlájùmọ̀lẹ́ Ọdẹ́tọ́lá (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kẹwàá) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1] Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà lédè Gẹ̀ẹ́sì, ṣùgbọ́n ní kété tó dára pọ̀ mọ́ tí èdè Yorùbá ní ìràwọ̀ rẹ̀ tàn.[2]
Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Jùmọ̀kẹ́ kàwé gírámà rẹ̀ ní Abẹ́òkúta Grammar School. Ó kàwé gboyè dìgírì rẹ̀ ní ifáfitì tí Ajayi Crowther University, níbi tí ó ti gbà ìwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ ìfitétí àti ìbánisọ̀rọ̀ nípa lílo ẹ̀rọ ìgbàlódé, kọ̀m̀pútà, lẹ́yìn èyí, ó tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní Federal University of Agriculture, Abẹ́òkúta, níbi tí ó ti kàwé gboyè dìgírì kejì nínú ìmọ̀ ìjìnlè kọ̀m̀pútà.[3]
Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Somewhere in the Dark[3]
- Glitterati[3]
- Bíńtà Òfegè[4]
- Heroes and Zeros[5]
- Lágídò[5]
- Bachelor's Eve[5]
- Alakiti[5]
- HigiHaga[5]
- Tinsel[5]
- The Return Of HigiHaga[5]
- Family Ties[5]
- Kanipe (2017)[6]
- Wetin Women Want (2018)[7]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Bada, Gbenga. "Boyfriends are distractions,' AMVCA's best indigenous act says". Pulse. Archived from the original on 2019-12-21. Retrieved 2018-04-08.
- ↑ "7 THINGS YOU PROBABLY DIDN’T KNOW ABOUT TALENTED ACTRESS, JUMOKE ODETOLA". Information Nigeria. January 24, 2018. Retrieved 2018-04-08.
- ↑ 3.0 3.1 3.2 Tofarati, Ige (January 28, 2018). "I can only act romantic roles with professionals– Jumoke Odetola". Punch. Retrieved 2018-04-08.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedvanguardcoverage
- ↑ 5.0 5.1 5.2 5.3 5.4 5.5 5.6 5.7 "Meet JUMOKE ODETOLA NEW NOLLYWOOD’S DELIGHT". BON Magazine. August 13, 2015. Archived from the original on 2019-12-21. Retrieved 2018-04-08.
- ↑ "Kanipe Full Cast and Crew". NList. January 1, 2017. Retrieved 2019-08-23.
- ↑ "After Successful Lagos Screening, New Flick, Wetin Women Want, Goes To Kwara". Eagle online. February 7, 2018. Retrieved 2018-04-08.