James Brown (internet personality)
James Brown | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | James Obialor 22 Oṣù Kejì 1999 |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | content creator, comedian, dancer and brand influencer |
James Obialor tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí James Brown ni wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kejì ọdún 1999 jẹ́ oníṣẹ́ orí ẹ̀rọ ayélujára, oníjó àti cross dresser tí ó di gbajú-gbajà ní ọdún 2018 látàrí fọ́nrán kan tí ó di tọ́rọ́ fọ́nkalé lórí ẹ̀rọ ayélujára tí wọ́n sọ wípé "They did not caught me" lẹ́yìn tí awọn ọlọ́pá mu.[1][2][3] Àwọn ni wọ́n múbpẹ̀lú àwọn ènìyan mẹ́rìndínláàdọ́ta kan tí wọ́n fura wípé wọ́n jẹ́ LGBT, tí wọ́n sì lo nkan bí oṣù kan ní ọgbà àtúnṣe tí ó wà ní Ìkòyí.[4][5] Lọ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ akitiyan, ilé-ẹ́jọ́ dá wọn sílẹ̀.[6]
James Brown gbé awonorin kan jáde ti ó pè ní "Hey Dulings" ní ọdún 2021.[7]
Ìjà oun ati Bobrisky
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní inú oṣù Kíní ọdún 2021, àwọn alábójútó Instagram ti ojú-ewé James Brown pa [8] lẹ́yìn tí ó ṣe fánrán kan tí ó fi sọ wípé Bobrisky fi ẹ̀sùn kan oun wípé oun ń ṣe bí Bobrisky pẹ́lú ìṣesí àti ara mímú oun, àti wípé Bobrisky déte ikú sí oun. [9] Bobrisky fi ẹ̀yìn ọwọ́ da ọ̀rọ̀ rẹ̀ nu, ó James sì ṣe fọ́nrán míràn láti bá Bobriaky lórí youtube.[10]
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ ""I no be upcoming Bobrisky"". BBC News Pidgin. 2020-07-20. Retrieved 2021-06-07.
- ↑ "James Brown (Nigeria) Biography; Net Worth, State Of Origin (Crossdresser)". ABTC (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-06-01. Retrieved 2021-06-07.
- ↑ Akpan, Solomon; Njoku, Kelechi Favour (2021-03-28). "Weird Skits Entertainers Do For Fame". Leadership News - Nigeria News, Breaking News, Politics and more (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-11. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Aanu, Damilare (2018-10-08). "Obialor James 'They didn't caught me' talks about living with HIV". Within Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-11. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Ojo, James (2021-04-23). "James Brown: I went to Ikoyi prison to become popular". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-11. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Owolawi, Taiwo (2020-10-27). "Nigerian star James Brown's homosexuality case dismissed by court". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-11.
- ↑ Odutuyo, Adeyinka (2021-03-30). "Following Burna's Grammy win, James Brown launches music career, drops single". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-07.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:0
- ↑ "Bobrisky has made himself my enemy –James Brown". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-01-17. Retrieved 2021-06-28.
- ↑ Alao, Abiodun (2021-01-17). "James Brown apologises to popular cross-dresser, Bobrisky". The Nation (Nigeria) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-11. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)