James Michel
Ìrísí
James Alix Michel | |
---|---|
Aare ile Ṣèíhẹ́lẹ́sì | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 16 April 2004 | |
Vice President | Danny Faure |
Asíwájú | France-Albert René |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Kẹjọ 1944 Mahé, Seychelles |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Lepep |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Natalie Michel |
James Alix Michel (ojoibi August 16, 1944) je oloselu ara Ṣèíhẹ́lẹ́sì to ti je politician who has been Aare ile Ṣèíhẹ́lẹ́sì lati 16 Osu Kerin, 2004. Teletele o je Igbakeji Aare labe asiwaju re, Aare France-Albert René, lati 1996 de 2004.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |