Danny Faure
Ìrísí
Danny Faure | |
---|---|
4th President of Seychelles | |
In office 16 October 2016 – 26 October 2020 | |
Vice President | Vincent Meriton |
Asíwájú | James Michel |
Arọ́pò | Wavel Ramkalawan |
Vice President of Seychelles | |
In office 1 July 2010 – 16 October 2016 | |
Ààrẹ | James Michel |
Asíwájú | Joseph Belmont |
Arọ́pò | Vincent Meriton |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 8 Oṣù Kàrún 1962 Kilembe, Protectorate of Uganda |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | United Seychelles Party |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Jeanine Decommarmond (div. 2016) Shermin Rudie Faure[1] |
Àwọn ọmọ | 5 |
Alma mater | University of Havana |
Danny Faure (tí a bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù karùn-ún ọdún 1962) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Seychelles tí ó jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ ède Seychelles láti ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹwàá ọdún 2016 di ọjọ́ kerìndínlọ́gbọ̀n oṣù kẹwàá ọdún 2020. Kí ó tó di ààrẹ, òun ni ó jẹ́ igbá kejì ààrẹ Seychelles láti ọdún 2010 di 2016. Faure jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú United Seychelles Party (PP).[2][3]
Ìpìlẹ̀ àti Ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Faure sí àwọn ìdílé Seychelles tí ó ń gbé ní Ìlú Kilembe tí ó wà ní gúúsù Uganda.[4] Ó ka ìwé prámárì àti Sẹ́kọ́ndírì rẹ̀ ní Seychelles. Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ Sáyẹ́nsì òṣèlú ní Yunifásítì Havana tí ó wà ní Cuba,[5][2][3][4][6]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Seychelles Vice President and wife divorce". www.seychellesnewsagency.com.
- ↑ 2.0 2.1 George Thande Quoting Reuters (16 October 2016). "Danny Faure sworn in as new president of Seychelles". Businessinsider.com. Archived from the original on 12 May 2019. Retrieved 18 October 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 3.0 3.1 Uranie, Sharon (16 October 2016). "Seychelles' new President: Danny Faure sworn in to office, calls for unity". Seychelles News Agency. Retrieved 18 October 2016.
- ↑ 4.0 4.1 "Explorers Directory". www.nationalgeographic.org. Archived from the original on 2021-10-09. Retrieved 2020-05-28.
- ↑ "The President - State House Seychelles | Office of the President". www.statehouse.gov.sc (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-24.
- ↑ "Danny Faure". Roscongress Building Trust. Retrieved 2020-05-28.