Joseph Belmont
Ìrísí
Joseph Belmont | |
---|---|
Vice President of Seychelles | |
In office 14 July 2004 – 30 June 2010 | |
Ààrẹ | James Michel |
Asíwájú | James Michel |
Arọ́pò | Danny Faure |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Mahé, Seychelles | 1 Oṣù Kẹfà 1947
Aláìsí | 28 January 2022 Victoria, Seychelles | (ọmọ ọdún 74)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | People’s Party |
Joseph Belmont (ọjọ́ kíní oṣù kẹfà ọdún 1947 – ọjọ́ kejìdílọ́gbọ̀n oṣù Kínní ọdún 2022) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Seychelles tí ó jẹ́ igbá kejì ààrẹ Seychelles láti ọjọ́ kẹrìnlá oṣù keje ọdun 2004 títí di ìgbà tí ó fẹ̀hìntì ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹfà ọdún 2010.[1] Ó dé ipò náà nígbà tí ààrẹ France-Albert René fi ipò rẹ̀ kalẹ̀ tí ìgbà kejì ààrẹ nígbà náà, James Michel, rọ́pò René gẹ́gẹ́ bí President. Belmont jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Seychelles People’s Progressive Front (SPPF)
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Vice-President Faure Takes Oath of Office". Official Website Of State House, Seychelles (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 28 January 2022.