Jump to content

Vincent Meriton

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Vincent Meriton
Vice President of Seychelles
In office
28 October 2016 – 27 October 2020
ÀàrẹDanny Faure
AsíwájúDanny Faure
Arọ́pòAhmed Afif
Minister of Community Development, Social Affairs and Sports
In office
20 July 2004 – 5 October 2016
ÀàrẹJames Michel
Arọ́pòMinistry disbanded
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Vincent Emmanuel Angelin Meriton

28 Oṣù Kejìlá 1959 (1959-12-28) (ọmọ ọdún 64)
Victoria, Seychelles
Ẹgbẹ́ olóṣèlúUnited Seychelles
OccupationPolitician

Vincent Emmanuel Angelin Meriton (tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kejìlá ọdún 1959) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Seychelles tí ó jẹ́ igbá kejì Ààrẹ láti ọdún 2016 títí di ọdún 2020.[1] Òun ni ó rọ́pò Danny Faure, àti Ààrẹ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Party.[2][3][4] Ó fi ìgbà kan jẹ́ mínísítà fún ọ̀rọ̀ àdúgbò àti eré ìdárayá.[5]

Ní oṣù karùn-ún ọdún 2024, a yàn fún ipò alága African Union fún ọdún 2025.[6]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Ahmed Afif inaugurated into office of the vice-president". http://www.nation.sc/articles/6646/ahmed-afif-inaugurated-into-office-of-the-vice-president. 
  2. "Vice-President Meriton, Designated Minister Mondon and Minister Larose Sworn in Office". Government of Seychelles. 28 October 2016. http://www.statehouse.gov.sc/news.php?news_id=3166. 
  3. "Vincent Meriton becomes vice-president, Macsuzy Mondon designated minister". Seychelles Nation. 28 October 2016. http://www.nation.sc/article.html?id=251596. 
  4. "People's Party Central Committee" Archived 2018-07-08 at the Wayback Machine., People's Party Website.
  5. Hajira Amla (27 November 2014). "Seychelles will not turn a blind eye to human trafficking, says Minister for Social Affairs". Seychelles News Agency. http://www.seychellesnewsagency.com/articles/1838/Seychelles+will+not+turn+a+blind+eye+to+human+trafficking%2C+says+Minister+for+Social+Affairs. 
  6. "Seychelles candidature – Chairperson of the African Union Commission". Foreign Affairs Department, Seychelles. 15 May 2024. Archived from the original on 15 May 2024. Retrieved 16 May 2024.