Janez Drnovsek

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Janez Drnovšek
Janez Drnovsek.jpg
President of Slovenia
Lórí àga
22 December 2002 – 23 December 2007
Aṣàkóso Àgbà Anton Rop
Janez Janša
Asíwájú Milan Kučan
Arọ́pò Danilo Türk
Prime Minister of Slovenia
Lórí àga
17 November 2000 – 11 December 2002
President Milan Kučan
Asíwájú Andrej Bajuk
Arọ́pò Anton Rop
Lórí àga
14 May 1992 – 3 May 2000
President Milan Kučan
Asíwájú Lojze Peterle
Arọ́pò Andrej Bajuk
President of Yugoslavia
Lórí àga
15 May 1989 – 15 May 1990
Aṣàkóso Àgbà Ante Marković
Asíwájú Raif Dizdarević
Arọ́pò Borisav Jović
Secretary General of the Non-Aligned Movement
Lórí àga
7 September 1989 – 15 May 1990
Asíwájú Robert Mugabe
Arọ́pò Borisav Jović
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí 17 Oṣù Kàrún, 1950(1950-05-17)
Celje, Yugoslavia (now Slovenia)
Aláìsí 23 Oṣù Kejì, 2008 (ọmọ ọdún 57)
Zaplana, Slovenia
Ẹgbẹ́ olóṣèlú Movement for Justice and Development (2006–2008)
Àwọn ìbáṣe
olóṣèlú mìíràn
League of Communists (Before 1990)
Liberal Democracy (1990–2006)
Tọkọtaya pẹ̀lú Majda Drnovšek (Divorced 1980)
Alma mater University of Ljubljana
University of Maribor

Janez Drnovsek (May 17, 1950 – February 23, 2008) A bí ní odún 1950. Ó jé olóòtú ìjoba Slovenia ní 1992 sí 2002. Léyìn èyí ni ó di àre ilè náà. Ní odún 1999 ni àìsàn kan n bá a jà ní kíndìnrín. Èkó nípa ‘economics’ ni ó kà. Ó sì di omo ilé asòfin ilè slovenia ni odún 1986. Isé ribiribi ni ó se láàrin odún méwàá tí ó fi se olóòtú ìjoba. Ó jé kí ilèr eè dara pò mó European union àti NATO ní 2004. Osù kéjìlá odún 2007 bí ó fi ipò àre ilè slovenia sílè. Ó kú nígbà tí ó di omo odún métàdínlógóta.