Robert Mugabe
Appearance
Robert Mugabe | |
---|---|
Ààrẹ orílẹ̀ èdè Zimbabwe tẹ́lè. | |
In office 31 December 1987 – 21 November 2017 | |
Alákóso Àgbà | Morgan Tsvangirai |
Vice President | Simon Muzenda Joseph Msika Joice Mujuru John Nkomo |
Asíwájú | Canaan Banana |
Arọ́pò | Emmerson Mnangagwa |
Prime Minister of Zimbabwe | |
In office 18 April 1980 – 31 December 1987 | |
Ààrẹ | Canaan Banana |
Asíwájú | Abel Muzorewa (Zimbabwe Rhodesia) |
Arọ́pò | Post abolished Revived 2009: Morgan Tsvangirai |
Secretary-General of the Non-Aligned Movement | |
In office 6 September 1986 – 7 September 1989 | |
Asíwájú | Zail Singh |
Arọ́pò | Janez Drnovsek |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Kutama, Salisbury, Southern Rhodesia | 21 Oṣù Kejì 1924
Aláìsí | 6 Oṣù Kẹ̀sán 2019 (ọmọ ọdún 95) |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | ZANU-PF (1987-2017) ZANU (1963–1987) ZAPU (1961–1963) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Sally Hayfron (deceased) Grace Marufu |
Alma mater | University of Fort Hare University of Oxford University of South Africa University of London |
Signature |
Robert Gabriel Mugabe (Pípè ní èdè Shona: [muɡaɓe], English: /mʊˈɡɑːbeɪ/ moo-GAH-bay; ojoibi 21 Oṣù Kejì 1924 - 6 Oṣù Kẹ̀sán 2019) jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Zimbabwe tẹ́lè. Ó jẹ́ ìkan lára àwọn ajàgbòmìnira fún orílẹ̀ èdè Zimbabwe. Ó jẹ́ alákóso orílẹ̀ èdè yí láti ọdún 1980 sí 1987 kí ó tó di ààrẹ.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Chan, Stephen (2003). Robert Mugabe: A Life of Power and Violence. p. 123.