Jump to content

Jay Boogie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jay Boogie
Ọjọ́ìbí26 Oṣù Kẹfà 1998 (1998-06-26) (ọmọ ọdún 26)
Port-Harcourt, Nigeria
Iṣẹ́Social media personality

Jay Boogie (tí a bí ní Ọjọ́ Kẹrindínlọ́gbọ̀n Oṣù Kẹfà, Ọdún 1998)[1] jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó nífẹ̀ẹ́ nínú oge àwọn tí ń yí ìdánimọ̀ wọn láti èyí tí wọ́n wà nígbà tí wọ́n bí wọn, ẹni tó ní ipa àti àgbajúmọ̀ lórí àwọn ìkànnì àjọlò lórí ẹ̀rọ ayélujára tí ó dá JaySecrets sílẹ̀. Ó di olókìkí lórí Instagram ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún ogún rẹ̀, pẹ̀lú ìyípadà ìbálòpọ̀ rẹ̀ tí ó ń gba àfiyèsí láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Nàìjíríà lórí àwọn ìkànnì àjọlò àwùjọ.[2] Boogie ti wà ní àkójọ láàárín àwọn tó máa ń wọṣọ ẹ̀yà ọ̀tọ̀ mẹ́wàá tí ó ga jùlọ ní Nàìjíríà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Bobrisky àti James Brown.[3] [4]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Ngwan, Nenpan (2022-12-09). "Who Is Jay Boogie the Cross-dresser and Has He Had Surgery?". Buzz Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-11. 
  2. "Jay Boogie: 'Nigerians prefer to welcome criminals into society than transgender pipo'". BBC News Pidgin. 2023-07-16. Retrieved 2023-10-11. 
  3. "Top 10 Cross Dressers In Nigeria, their Biography, Net-worth & More" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-01-06. Retrieved 2023-10-11. 
  4. Azeez, Fatimat (2023-06-16). "Top 10 Nigerian Cross-Dressers (2023)". rnn.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-11.