Jeļena Ostapenko

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jeļena Ostapenko
Ostapenko at the 2019 French Open
Orílẹ̀-èdèÀdàkọ:LAT
IbùgbéRiga, Latvia
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kẹfà 1997 (1997-06-08) (ọmọ ọdún 26)
Riga, Latvia
Ìga1.77 m
Ìgbà tódi oníwọ̀fà23 April 2012[1]
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (two-handed backhand)
Olùkọ́niMarion Bartoli[2]
Ẹ̀bùn owóUS$ 8,877,147
Ẹnìkan
Iye ìdíje237–145 (62.04%)
Iye ife-ẹ̀yẹ3
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 5 (19 March 2018)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 41 (16 March 2020)
Grand Slam Singles results
Open Austrálíà3R (2017, 2018)
Open FránsìW (2017)
WimbledonSF (2018)
Open Amẹ́ríkà3R (2017, 2018, 2019)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje WTARR (2017)
Ẹniméjì
Iye ìdíje118–87 (57.56%)
Iye ife-ẹ̀yẹ3
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 17 (2 March 2020)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 17 (16 March 2020)
Grand Slam Doubles results
Open AustrálíàQF (2020)
Open FránsìQF (2019)
Wimbledon3R (2016, 2018)
Open Amẹ́ríkàQF (2019)
Grand Slam Mixed Doubles results
Open Austrálíà2R (2020)
Open Fránsì1R (2017)
WimbledonF (2019)
Open Amẹ́ríkà2R (2017)
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò
Fed Cup31–17 (64.58%)
Last updated on: 31 March 2020.

Jeļena Ostapenko (ọjọ́ìbí 8 June 1997), wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi Aļona Ostapenko,[3] ni agbá tẹ́nìs ará Latvia. Ipò WTA rẹ̀ láàgbáyé tó gajùlọ ni No. 5 nínú àwọn ìdíje ẹnìkan tó dé bẹ̀ ní 19 March 2018, àti No. 17 nínú àwọn ìdíje ẹnimẹ́jì, tó dé bẹ̀ ní 2 March 2020. Ostapenko gba ife-ẹ̀yẹ Open Fránsì odun 2017 nígbà tó bori Simona Halep ní ìparí.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Player Index: Jelena Ostapenko". WTA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 
  2. also Glenn Schaap (2018-2019), Jeļena Jakovļeva (her mother), Anabel Medina Garrigues (2017), David Taylor (2018)
  3. "Aļona Ostapenko: 'Neviens mani nav tā apmācījis. Tas vienkārši ir stils, kurā spēlēju'" (in lv). Latvijas Avīze. 12 June 2017. http://www.la.lv/alona-ostapenko-neviens-mani-nav-ta-apmacijis-tas-vienkarsi-ir-stils-kura-speleju/. Retrieved 12 June 2017.