Jenifa
Ìrísí
Jénífà | |
---|---|
Fáìlì:Movie poster for Jenifa.jpg | |
Adarí | Muhydeen S. Ayinde |
Olùgbékalẹ̀ | Olatunji Balogun |
Àwọn òṣèré | Funke Akindele Iyabo Ojo Ronke Odusanya Eniola Badmus Mosunmola Filani Ireti Osayemi Tope Adebayo |
Orin | Fatai Izebe |
Ìyàwòrán sinimá | Moroof Fadairo |
Olóòtú | Abiodun Adeoye |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Scene One Productions |
Olùpín | Olasco Films Nig. Ltd. |
Déètì àgbéjáde |
|
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | Yoruba |
Jénífà jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín ti ọdún 2008 láti ọwọ́ Funke Akindele. Fíìmù náà gba àmì-ẹ̀yẹ mẹ́rin ní ọdún 2009 láti ọwọ́ Africa Movie Academy Awards, bí i òṣèrébìnrin tó dára jù lọ, Best Original Soundtrack àti fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà tó dára jù lọ. Akindele gba àmì-ẹ̀yẹ òṣèrébìnrin tó dára jù lọ ní ayẹyẹ Africa Movie Academy Awards fún ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù yìí.[1][2][3][4]
Fíìmù yìí jẹ́ àgbéjáde àkọ́kọ́ tó wá padà gbajúmọ̀ ní Nàìjíríà. Apá kejì rẹ̀ jáde ní ọdún 2011, wọ́n sì tún ṣe àgbéjáde eré kúkurú irú rẹ̀ ní ọdún 2014.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Ajayi, Segun (11 April 2009). "Nollywood in limbo as Kenya, South Africa rule AMAA Awards". Daily Sun (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 2 January 2010. https://web.archive.org/web/20100102122208/http://sunnewsonline.com/webpages/features/blockbuster/2009/apr/11/blockbuster-11-04-2009-001.htm. Retrieved 8 March 2011.
- ↑ Okon-Ekong, Nseobong (10 July 2010). "Funke (jenifa) Akindele - How to Lose Your Name to a Character". AllAfrica.com (AllAfrica Global Media). http://allafrica.com/stories/201007120708.html. Retrieved 8 March 2011.
- ↑ Amatus, Azuh (10 April 2009). "AMAA 2009: How Nollywood took the back seat". Daily Sun (Lagos, Nigeria). http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/showtime/2009/apr/10/showtime-10-04-2009-002.htm. Retrieved 8 March 2011.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "AMAA Nominees and Winners 2009". Lagos, Nigeria: Africa Movie Academy Awards. Archived from the original on 5 April 2011. Retrieved 8 March 2011. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)