Jeremiah Omoto Fufeyin
Ìrísí
Jeremiah Omoto Fufeyin | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 15 February 1971 Burutu, Delta State, Nigeria |
Iṣẹ́ | Televangelist minister, philanthropist |
Ìgbà iṣẹ́ | 2010 - present |
Organization | Christ MercyLand Deliverance Ministry (CMDM) |
Olólùfẹ́ | Anthonia Fufeyin |
Àwọn ọmọ | 5 |
Website | christmercyland.org |
Jeremiah Omoto Fufeyin (tí wọ́n bí ní 15 February 1971, sí Burutu, ní Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà) jẹ́ olùdásílẹ̀ àti wòlíì àgbà ti ìjọ Christ Mercyland Deliverance Ministry (CMDM), Effurun, Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà, Nàìjíríà.[1] Ó ṣe ìdásílẹ̀ ìjọ náà ní 3 April 2010.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ẹbí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Jeremiah Omoto Fufeyin sí ìlú Burutu, ní Warri, ìpínlẹ̀ Delta, Nàìjíríà ní 15 February 1971.[2] Ó ṣe ètò ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní Zuokumor Primary School ní Burutu L.G.A ti ìpínlẹ̀ Delta láàrin ọdún 1981 sí 1986.[3] Ó lọ sí ilé-ìwé girama rẹ̀ ní Gbesa Grammar School Ojobo, láàrin ọdún 1986 sí 1992.[4]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Prophet Fufeyin urges wealthy pastors to assist less-privileged". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-19. Archived from the original on 2022-03-15. Retrieved 2022-03-15.
- ↑ Fufeyin, Jeremiah (31 May 2015). "I am not Junior TB Joshua —Fufeyin of MercyLand - Vanguard News". http://www.vanguardngr.com/2015/05/i-am-not-junior-tb-joshua-fufeyin-of-mercyland/.
- ↑ "Prophet Series:Nigeria's globally recognized prophets (1)". Openlife (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-21. Retrieved 2020-05-30.
- ↑ daylight Nigeria, Prophet Jeremiah: Liberating souls, changing lives, through power of God, 3 September 2016