Ìpínlẹ̀ Delta
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà)
Ìpínlẹ̀ Delta State nickname: The Big Heart | ||
Location | ||
---|---|---|
Statistics | ||
Governor (List) |
Emmanuel Uduaghan (PDP) | |
Date Created | 27 August 1991 | |
Capital | Asaba | |
Area | 17,698 km² Ranked 23rd | |
Population 1991 Census 2005 estimate |
Ranked 9th 2,570,181 4,710,214 | |
ISO 3166-2 | NG-DE |
Ipinle Delta jẹ́ ọ̀kanIlára àwọn Ìpínlẹ̀ nií riílẹ̀-èdèNaijiria. Ìpínlẹ̀ Delta wà ní apá Gúúsù Nàìjíríà. Adá Ìpínlẹ̀ ìíkalẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n, oṣù keẹjọ ọdún 1991lábé ìjọba Gen. Ibrahim Babangida [1]. Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Delta ni Asaba, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ìlú Warri ni àárín ajé Ìpínlẹ̀ Delta. Àwọn èyà tí ópọ̀ jùlọ í Ìpinlè Delta ni Igbo, Urhobo, Isoko, Ijaw, Itsekiri [2]. Ìpinlè Delta ní Ìjọba Àgbègbè Ìbílè márùndílọ́gbọ̀n (25) [3] Gómìnà Ifeanyi Okowa ní gómìnà Ìpínlẹ̀ Delta lọ́wọ́.
Awon Ìjoba Agbegbe Ìbílè ti Delta
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Ariwa Aniocha
- Guusu Aniocha
- Bomadi
- Burutu
- Guusu Ethiope
- Ila-oorun Ethiope
- Ariwa Ila-oorun Ika
- Guusu Ika
- Ariwa Isoko
- Guusu Isoko
- Ila-oorun Ndokwa
- ìwọ̀ oòrùn Ndokwa
- Okpe
- Ariwa Oshimili
- Guusu Oshimili
- Patani
- Sapele
- Udu
- Ariwa Ughelli
- Guusu Ughelli
- Ukwuani
- Uvwie
- Ariwa Warri
- Guusu Warri
- Guusu ìwọ̀ oòrùn Warri
Àwọn olókìkí ènìyàn láti Delta
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Kefee, olori obinrin ati ko-orin Naijiria
- Sunny Ofehe, olóṣèlú àti ajàfún òmìnira
- Isaiah Ogedegbe, kọrinaọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà[4]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Brief History of Delta State:: Nigeria Information & Guide". Nigeriagalleria. 1991-08-27. Retrieved 2022-03-26.
- ↑ "Delta State, Nigeria Genealogy". FamilySearch Wiki. 2020-04-11. Retrieved 2022-03-26.
- ↑ "Local Government Areas in Delta State". Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria. Retrieved 2022-03-26.
- ↑ Alaka, Gboyega; Ogunlade, Adeola (13 June 2023). "Iginla, TeeMac, others eulogise TB Joshua at posthumous birthday". The Nation Newspaper. Archived from the original on 13 June 2023. Retrieved 23 October 2023.